Igbagbo opolopo okunrin laye ode oni ni wi pe ko si obinrin ti won le ba nile mo lode iwoyi. Lara awon okunrin to gba bee ni ogbeni Dada-Stephen Dst. O fi eyi han ninu atejade re to fi si ori iwe oju (facebook). Eyi ni ohun ti arakunrin naa le:
Ibele je ebun pataki fun igbeyawo ti okunrin maa n gba lati owo iyawo re titun. Sugbon lode oni, ko si ohun to jo bee mo, nitori ninu ki won ti fi se ebun ojo ibi, tabi fifi se idupe oore, won tun le fi se ona kan lati fi wase, won tun letun ti fi se iyinrere ninu ile ijosin, awon miran n lo ibale won fun ona lati fi yege idanwo, tabi ki won ti fi se owo oni moto ti won wo. { ede geesi lo koo awa la tumo re}
Eyi ni eda bi arakunrin naa se ko oo
Sugbon orísìírísìí idahun ati esi ni àwon eniyan lokunrin ati lobinrin ti n fun ògbéni Dada. Awon kan kin leyin awon kan si benu ate luu. Eyi ni die ninu awon esi ati idahun naa:Eyi ni eda bi arakunrin naa se ko oo
Ni ero ti yin nje eyin faramo oro ogbeni Dada yii
Ati hmmmm, ati heeenn lori Gbayiii naa ni
No comments:
Post a Comment