propeller

Propellerads

Monday, 12 December 2016

E wo iru iya ti won fi n je kopa ni ago idanileko igbaradi. Nibo ni oro NYSC nlo ni orile ede yii.

 Se gbogbo wa la ranti ni igba ewe wa ti awon oluko wa maa n so wi pe E KUNLE KE KAWO SOKE KE SI DIJU YIN. Iyalenu nla ni aworan awon agunbanirao kan ti o wa ni ago idanileko igbaradi. Aworan yii ti bere si ni ja rainrain lori ayelujara.
Gege bi a se ri ni ori oju ewe naij.com wi pe isele naa sele ni ago idanileko igbaradi (orientation camp) Umunna, Bende ni ijoba ibile Abia. Eyi ni ohun ti won ko:
Mo je agunbaniro to wa ni ago idanileko igbaradi NYSC ni Umunna, Bende ni ipinle Abia. Ni owuro yii, lasiko ti a se igbaradi yiyan bi ologun, awon kopa ti won wa ni ile kesan-an mu inu bi ologun ti o n dari won o si fi iya je won pelu pe ki won kunle kawo soke fun bi iseju meloo kan ki o to fi won sile. #Iyen ni wi pe ki eniyan ka iwe dori gbi ko ni ki a ma fi iya omo jeleosinmi je #
"I am a corp member currently undergoing orientation course at the NYSC orientation camp, Umunna, Bende, Abia state. This morning, during parade rehearsals, some corp members in 9 Platoon got the platoon inspector annoyed and he punished them by kneeling them down for some time before releasing them. #Even graduates still get kindergarten punishments #
Aworan naa re ni isale yii:


Airinjina lai ri abuke okere, baa ba rin titi a oo ri pepeye to pon omo
Iyalenu ni oro awon kopa ati ajo NYSC n je fun wa ni odun yii oo. Bi kopa ko ba ku, won yoo ji kopa gbe tabi ki won fi iya aito je kopa. Gbogbo re lori pe a n sin ilu baba eni naa ni. Hmmmm

Gbogbo re naa lori Gbayii naa ni
 

No comments:

Post a Comment