propeller

Propellerads

Tuesday, 6 December 2016

Ile-iwe wo ni copa yii ti jade. Ewo bi kopa yii se yeye ara re lori facebook. Talo moo

 Erin keekee lo gba enu awon eniyan, awon kan si bere si ni bu arabinrin ti o n si ilu baba re yii gege bi agunbaniro. Favour Abejirin ni inu re dun titi ni ago idanileko fun igbaradi (orientation camp) to si bo si ori iwe oju (facebook) lati ko akanse orin NYSC ti awon agunbaniro maa n ko fun awon eniyan. Sugbon dipo ki arabinrin naa gba oriyin, o seni laanu wi pe nise lo te, to si fi ate te idi. Eyin naa e wo ohun ti Favour ko:
Obeying d Clarion’s call,,,,,, Under d sun or either rain,,,,, wit Education and selflessness.

dipo ki o ko “Youth obey the Clarion’s call…..Under the sun or in the rain…. with dedication and selflessness.”
Opolopo lo fi Abejirin se yeye, awon kan si bere si ni bu pe ko daju wi pe o mowe titi to fi jade ni ile eko ifafiti. Sebi ohun ti a o ba mo, o ye ki a bere ni.

O ga ooo

Gbayii fun gbogbo kopa
 

No comments:

Post a Comment