Iroyin yajoyajo to towa lowo jabo wi pe Mulikatu to ti je aya Sikiru Adesina {arakangudu} jade laye lo nii. Gege bi a se ri gbo lati oju iwe {facebook} Taiwo Alimi o ko sibe wi pe: IKU TUN TI DORO OO. SUN RE OO EGBON MI. {ede gee si lo fi ko o}
Ti e o ba gbagbe ninu odun yii ni oloogbe Sikiru Adesina to ti je oko Mulikatu naa jade laye, ki aya naa to jade laye bayii. Hmmm, Tokotaya Arakangudu e sun reooo. Titi di asiko ti a n ko iroyin yi jo, pato ohun to fa iku arabinrin naa koi ti ye wa. Sugbon a oo fi ekun rere iroyin naa too yi leti ni kete ti a ba ti gboo.
Hmmmmmm.
Ki la o fi Olorun se ninu idajo re leyin ka tun so fun pe
Gbayiiiii
No comments:
Post a Comment