propeller

Propellerads

Thursday, 3 November 2016

Dáhùn ìbéèrè kékeré yìí kí o sì je̩ è̩bùn e̩gbè̩rún méta náírà (N3000).




Láti ilé is̩é̩ Kolazad Group of Companies wó̩n ní kí a s̩e ìrántí àwo̩n Ako̩ni ló̩nà ìbéèrè. Alás̩e̩ ilé is̩é̩ Kolazad Group of Company Ò̩gbé̩ni Kó̩láwo̩lé Azeez ní òun yóò fún e̩niké̩ni tó bá gba ìbéèrè náà ni e̩gbè̩rún méta náírà (N3000). È̩bùn náà lè kéré s̩ùgbó̩n ìrántí àwo̩n ako̩ni wa s̩e pàtàkì púpò̩ àti wí pé fún àǹfàní àwo̩n tí kò mò̩ wó̩n yóò tún ní àǹfàní láti mò̩ wó̩n.

Dáhùn ìbéèrè yìí nípa àwo̩n ako̩ni eléré onís̩e yìí kí o sì je̩ è̩bùn e̩gbè̩rún méta náírà.

1. Kíni orúko̩ àwo̩n òs̩èré yìí?
2. Kíni orúko̩ tí ò̩pò̩lo̩pò̩ ènìyàn mò̩ wó̩n sí
3. O̩dún wo ni wó̩n kú
4. Dárúko̩ fíìmù kan tí o ti rí wo̩n rí.
(Kò sí è̩bùn fún ààbo̩ ìdáhùn)







Fi ìdáhùn re̩ ráns̩é̩ si 08030627995{yálà whatsapp tàbí àtè̩ráns̩é} tàbí babayorubame@gmail.com tàbí lórí ojúìwé (facebook) Kolawole Azeez Baba Yoruba

Gege bi e se mo pe Gbayii naa lo ma gbeyin ohun ti a ba ko

No comments:

Post a Comment