Lasiko ipolongo idibo
Amerika orisiirisii nnkan ni Aare ti won dibo yan, alagba Donald Trump ni oun
yoo se ti oun ba ti wole gege bi aare, bakan naa lo si so awon oro kan to ta
bale ta boko lasiko naa. Lara re ni awon nnkan ti a oo menu ba yii. O ku siyin
lowo lati gbee yewo boya oro naa to si Trump leu gege bi aaare ti won dibo yan.
- N o le gbogbo awon omo orile ede alawo dudu pada si ilu won paapaa julo orile ede Naijiria.
- A o gbe ote le gbogbo Musulumi ni ameriaka nitori won fi eto ibanilopo dun ni. (E wo fidio re nibi)
- Iroyin tun gbe pe orisirisii oro kobakungbe ni Trump so si awon obinrin ni Amerika nipa se Hilary Clinton
- E ma gbagbe pe won fi esun fifi ihoho ara eni han kan iyawo Trump. Eyin naa e wo awon aworan iyawo aare tuntun naa ni isale yii.
Sugbon leyin idibo naa
ti Trump wo le gege bi Aare tan iyalenu lo je wi pe opolopo awon ohun ti ogbeni
naa so ni o ti n ko je tabi ka so wi pe o ti n yii pada.
- Nipa gbolohun to so wi pe ohun yoo le gbogbo alawo dudu pada si ilu won, won ti yo oju ewe naa kuro lori oju ewe alatagba Trump, won ni alagba naa ko so oro naa nitori eleya meya sugbon nitori iwa buruku to kun owo awon olori orile ede adulawo, paapaa julo orile ede Naijiria. (e gbo se iro lo pa, sugbon se ori bibe logun ori fifo). Sugbon pelu pe won ni awon ko ka oro naa kun to, Trump ko gbe ipe aare Buhari nigba ti o pee lati ki ku orire. Se oro naa ko ti n se bo, bayii
- Leyin ti Trump ti ni ohun yoo foju gbogbo Musulumi Amerika ri mabo. Won tun ti yoo gbedeke ti won fe fi le awon musulumi naa kuro. Won salaye pe gbolohun naa kiise nitori esin sugbon nitori wahala awon alakata kiti esin ti won yin ado oloro kaakiri agbaye ati nitori ofin masu mato ti seria awon Musulumi n se nipa ako si abo. (Ni ero tiwa, ti Trump ba yo ote yii kuro loju se ko ni wuu niwa sa? Hmmm ewu n be loko longe oo, longe funra re, ewu ni. Musulumi Amerika e fura oo).
- Opolopo Obinrin ni ile Amerika lo tako idibo fun Donald Trump ti won si ni awon ko ni dibo fun. Sugbon ninu ipolongo re lo ti tu asiri bi Aare ana Clinton oko oludije Hilary Clinton se ba obinrin kan sun ni ofisi re ti asiri tun ti iyawo re (iyen Hilary Clinton) si lo owo agbara pe eni to ba tako oko ohun nigba naa yoo pe lewon. O wa so wi pe obinrin to le bo abosi oko re nigba yen, se ko ni bo abosi ara re ni gbogbo ona. Idi niyi to fi ni bakan naa ni gbogbo obinrin ri to fi ni ki won ma dibo fun Hilary Clinton. (E jowo se looto lo je wi pe bakan naa ni gbogbo obinri ri).
- Eyin naa e tun wo awon aworan iyawo aare Amerika. Nigba ti iyawo aare ba le se bayi sori ero ayelujare, kini awon omo orile ede to ku yoo se. Sugbon won ni igba aimo ni arabinrin naa ti ya awon aworan naa. (Egbo imi kinkin leti awo gbegiri, baaba nu kuro loju tokan nko. Ohun taaba se loni oro itan ni lola oo.)
Iroyin miran ree: Asiri
bi Donald Trump se jawe olubori ninu eto idibo Amerika
Ju gbogbo re lo Aare
Trump E ku oriire oooooooooo.
Amerika, E ku amojuba
Aare tuntun oooooo
Orile ede agbaye e ku
hmmmmmmm. (Eyi to ba koju siyin ni ke fi si)
Gbayii naa ni gbogbo
re.
No comments:
Post a Comment