Gege bi iroyin se fi to wa leti; arakunrin kan ati arabirin kan ti won ni aarun opolo (weere) ni won se ohun to ya opolopo eniyan lenu ni ilu Bayelsa. Pelu pe won je olode ori to, arun naa ko sewon de ibi fifi ife han si ara won. Ni ita gbangba ni won ti n fi enu ko arawon lenu ti won si n di mo ara won gege bii loko laya.
Gege bi Arakunrin Imalah Ugoachanum to jabo iroyin naa se so loju iwe (Facebook) re
O je ka mo wi pe awon ololufe naa fi ife naa han to be gee ti gbo ero fi pe le won lori lati woran, awo dami enu.
Iroyin tun fi to wa leti pe arabirin weere naa ti ni oyun sinu, ni eyi to si je wi pe Arakunrin ololufe re ti won jo je weere lo ni oyun naa.
Hmmmm, weere dun n wo sugbon ko see bi lomo.
Yala yoo san tabi koni san Edumare Oba ko ni fi weere dan wa wo.
Ni ero tire nje iwo gba pe weere niwo bi?
Gbayii fun gbogbo eyin ololufe iroyin wa.
No comments:
Post a Comment