Jije osere fiimu ni orile ede Naijiria, nje o to gege bi ona lati fise se lai fi nnkan miran kun fun eniyan?
Gege bi oro orile ede Naijiria ti ri bayii nipa sise ayederu ise eni, isoro ti o n koju eto oro aje, ati awon ipenija orisiirisii to ku. Ni ero tiyin, nje eyin ro wi pe jije osere ni orile ede Naijiria to lati mu gege bi ona kan soso lati mu owo wole fun eniyan?
Igbagbo opo eniyan ni wi pe ti o ba ti gbajugbaja lati ipase ero amohunmaworan, iyen ja si wi pe lona kan tabi omiran olowo ni e. Nipa idi eyi opolopo eniyan lo n wu lati darapo mo awon osere naa ni gbogbo ona to wu ti ki baa je.
Sugbon Paga!! Ibi ti won fuju si ona ko gbabe ibe rara fun opolopo awon osere naa. Pelu gbogbo iyi ati aponle ti won ri ninu ise naa, won ko yato si awon ara ilu ti ko si owo lowo re kan lo titi (Iyi lari ko si owo). Bee si ni opolopo n ri owo jaburata nidii ise naa.
Ibeere ibe wa ni wi pe
- Kini eyin ro wi pe awon ti won rise, lowo nidi ise naa se si i ti won fi rowo mu nidi ise naa?
- Ni ero tiyin, kini e lero wi pe awon to ku die kaa to fun nidi ise naa le se ti oro won naa yoo fi ja sayo nibi sise fiimu ni orile ede Naijiri?
Bakan naa e le ri alemode yii ka ni ede geesi (oyinbo) lori: http://babayorubaonthebroadcast.blogspot.com.ng/2016/10/acting-as-nollywood-curse-or-blessing.html
No comments:
Post a Comment