Òrò yí pa mí léèrín nígbà tí mo rí i. Sùgbón ohun tí mo rò ni wí pé mò n lá àlá ni. E jòwó kí enìkan tètè jí mi lójú orun, kí ilé agódo Fújì tó gbiná oo.
Òsùpá n kùnlè fún Pàsúmà
Kíni èrò tiyín nípa àwòrán yìí? Nítorí ní tèmi àwòrán yìí dàbí eni wí pé iná n jó lórí òrùlé ni.
- Tí èyin bá jé olólùfé Pàsúmà, njé èyín gba àwòrán yìí gbó?
- Tí èyin bá jé olólùfé Òsùpá, njé èyín gbà pé irú èyí lè selè.
G
Gb
Gba
Gbay
Gbayi
Gbayiiii náà ni mo fé so gégé bí e ti mò.
E má gbàgbé láti ye àlèmóde yìí wò ní ìkànnì wa ní èdè gèésì lórí: http://babayorubaonthebroadcast.blogspot.com.ng/2016/10/osupa-and-pasuma-settle-their-dispute.html?m=1
No comments:
Post a Comment