propeller

Propellerads

Sunday, 9 October 2016

Oluranlowo Alagba ijo fi tipa ba omo Alagba (omo odun meta) sun, idi to fi se bee yoo ya yin lenu

Arakunrin kan to je omo odun mejidinlogbon (28) ti oruko re n je Ogbeni Bethel Samuel ni won fi esun ifipabanilopo kan pelu omo odun meta. Gege bi iwe iroyin Vanugard se so, Samuel jewo yii fun awon olopa ipinle Rivers. Isele yii sele ni adugbo Rumuolumeni ni ijoba ibile Obio/Akpor. Arakunrin yii ni olowo otun alagba ijo Pentecostal ni ilu Port Harcourt. Samuel se alaye wi pe Esu lo ti ohun si ibi iwa omugo naa.
Bawo ni oro naa se sele?
Ni ojo buruku yii,  emi ati oga mi n se ipale mo fun isoji ita gbangba ti a fe se, a si gbera lati bere si ni maa le alemode kiri. Nigba ti a ti ri jina si ile ni oga mi deede pemi wi pe awon gbagbe lati mu owo jade wi pe kin sare lo ba awon mu u owo die wa nile ka to maa ba ise naa lo. Nigba ti mo dele, mo ri awon omode kekeke ti won n sere mo si tan okan ninu won si koro, mo si tipa tipa baalo, awon to ku re ni wo se ofofo oro naa.
Samuel se alaye siwaju wi pe ise Esu ni iwa naa je foun ati wi pe oun o mo ohun to sele si oun nigba ti oun hu iwa yii.
Ohun to dami loju ni wi pe inu mi ko dun si isele yii, mo wa fi akoko yi be gbogbo obi ati alagbato pe ki won fori ji mi, ti won ba fun mi ni anfaani leekan si iru eyi ko je se omo lowo mi mo. Ise esu ni.
To ba je eyin ni alagba naa ki le maa se
Gbayii fun gbogbo eyin temi

No comments:

Post a Comment