Se bí wón ní ibi tá a bá pè lórí enìkan kò gbodò fi tilè. Òrò yí kò rí béè lódò àwon omo orílè èdè Nàìjíríà kan. E wo àwon àwòrán ìsàlè yí kí e rí àwon àbùkù tí wón fi kan àwon olórí orílè èdè yí.
1. Bó tilè jé wí pé jagunjagun ni Bùhárí télè ri, sé irú jagunjagun báyìí wá ni
2. Lásìkò ayeye ìfisípò egbó sé ohun tí wón n so rèé
3. Haaa sé òrò rèé ní ìgboro enu, níbi ayeye ìfisípò
4. Èru kí ló fé ba àwon Baba yìí nínú òrò Bùhárí? Wón mà n tún fìlà se ni
5. Ilé isé ìbánisòrò wo ló so èyí? Bóyá nítorí lílo bíbò ààre ló fa èyí
6. Sé béè ni ààre luko tó ni abí kíni eyí? Ó mà lè jé àsìkò ìrun ni wón wò
7. Níse ni wón tún so Bùhárí di Buharilin dípò Merlin níbí
8. Sé wón ñ so pé inú n bi Tinubu si Bùhárí ni?
9. Sebí wón ti rí ìwé èrí náà ki ààre tó wolé, àbí kí tún ló fa èyí?
10. Bí Baba bá tiè ní ìpèníjà etí, sé óyé kí e fi èébú ara bú olórí orílè èdè yí?
11. Sé òrò yí rí béè lóòótó?
BÀBÁ YORÙBÁ èmi ò róba fín o, nítorí aróba fín loba n pa.
Gbayii fún Ààre Muhammad Bùhárí
No comments:
Post a Comment