Àánú
ìkúnlè̩ abiyamo̩ s̩e mí nígbà tí mo rí ìròyìn yí ní ojúìwé ò̩ré̩
mi kan mo sì
rò wí pé ó ye̩ kí n mú u wá sí ojú ìwòràn láti kà fún è̩yin olólùfé̩
mi gé̩gé̩ bí ìkéde ìdáàbò bo e̩ni ló̩wó̩ ikú fún àwo̩n o̩mo̩ wa.
Kay Yusuf Sanni ko̩ó̩ síbè̩ wí pé:
Àánú
àwo̩n òbí rè̩ ló s̩e mí, kìí s̩e ti o̩mo̩ tó pa ara rè̩
Lé̩tà
tó ko̩ kó tó pa ara rè̩
Gé̩gé̩
bi a s̩e gbó̩, are̩wà o̩mo̩bìnrin yìí, tó jé̩ o̩mo̩ o̩dún méjìdínlógún
tó parí ilé è̩kó̩ sé̩kó̩ndírì ní nǹkan bíi ò̩sè̩ mélòó kan sé̩yìn,
tí ó sì lè jé̩ wí pé òun ni kì bá je̩ olorí orílè̩ èdè yìí, ló
pa ara rè̩ láìpé̩ yìí nítorí ò̩ré̩kùnrin rè̩ fi sílè̩ tó sì bá
e̩lòmíràn lo̩ (ò̩ré̩ o̩mo̩bìnrin tó pa ara rè̩) ní o̩jó̩ ke̩rìndínló̩gbò̩n
os̩ù keje. (Kay Yusuf Sanni ko̩ó̩
ní èdè gè̩é̩sì, àwa la túu sí èdè Yorùbá)
Kíni
e rò nípa o̩mo̩bìnrin yìí?
Ó
ga ooo
Nítorí
mo ti lòó ti pé̩, e̩ rò wí pé mi ò ní so̩ó̩ mó̩, s̩ùgbó̩n iró̩ ni,
mo s̩i máa máa so̩ wí pe GBAYÌÌ fún è̩yin tèmi
Ju gbogbo rè̩ lo̩, e̩ lè ka ìròyìn yìí ní èdè gè̩é̩sì lórí: http://babayorubaonthebroadcast.blogspot.com.ng/2016/10/life-saving-information-see-how-this.html
No comments:
Post a Comment