Olushina Olabode OmoiyaShina(eni tó te òrò náà)
Ìsíwò ó, Ìwòrì wò ó, Ohun táa bá jìjo ro gígún ní gún. Arákùnrin kan ni òrò obìnri ní fífé ti n dàláàmú, tó sì nílò àmòràn èyin ènìyàn kí ó ba máà gbé eegun eléegun.Gégé bí ògbéni Olushina Olabode OmoiyaShina se tèé sí ojú ìwé (Facebook) re wí pé:
E jòwó èyin ènìyàn mi, e jé ká jo gbé òrò yí yèwò, kí e dè bámi fún òré mi ní ònà àbáyo
Ó ní òrébìnrin márùn-ún(5), kò sì mo èyí tí kò bá fé nínú won.
1. Obìnrin tí won o tíì já ìbálé rè sùgbón kò níwà
2. Obìnrin tó lówó, lórò sùgbón ó yándìí (alágbèrè)
3. Òjògbón àti òmòwé bìnrin sùgbón o ya òbun
4. Obìnrin tó lésin sùgbón ó n jalè
5. Obìnrin tó ní gbogbo ohun tí okùnrin n fé sùgbón kò lè bímo
Èyin gégé bí enìkan tani, èyin yóò fé nínú àwon obìnrin wònyí, tàbí èwo le máa gba òré mi ní àmòràn láti fé.
Òrò rèé oo èyin òjògbón, èwo ni ká se ooo
E ti mò pe Gbayii náà ni ma fi gtbèyìn
No comments:
Post a Comment